Judges 5:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni ibukun jùlọ ni Jaeli láàrin àwọn obinrin, Jaeli, aya Heberi, ọmọ Keni, ẹni ibukun jùlọ láàrin àwọn obinrin tí ń gbé inú àgọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun Jaeli aya Heberi ọmọ Keni jù awọn obinrin lọ, ibukún ni fun u jù awọn obinrin lọ ninu agọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Alábùkún jùlọ nínú àwọn ọmọ obìnrin ni Jáélì, aya Hébérì ará Kénì, alábùkún jùlọ nínú àwọn obìnrin tí ń gbé inú àgọ́.