Judges 5:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Omi ni Sisera bèèrè, wàrà ni Jaeli fún un, àwo tí wọ́n fi ń gbé oúnjẹ fún ọba ni ó fi gbé e fún un mu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O bère omi, o fun u ni warà; o mu ori-amọ tọ̀ ọ wá ninu awo iyebiye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó bèèrè omi, ó fún un ní wàrà; ó fi àwo iyebíye tí ó yẹ fún àwọn ọlọ́la fún un ni wàrà dídì.