Judges 5:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọlọ́gbọ́n jùlọ ninu àwọn obinrin tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ dá a lóhùn, òun náà sì ń wí fún ara rẹ̀ pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn obinrin rẹ̀ amoye da a lohùn, ani, on si ti da ara rẹ̀ lohùn pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn amòye obìnrin rẹ̀ dá a lóhùn; àní òun náà pẹ̀lú ti dá ara rẹ̀ lóhùn pé,