Judges 5:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, nígbà tí o jáde lọ láti òkè Seiri, nígbà tí o jáde lọ láti agbègbè Edomu, ilẹ̀ mì tìtì, omi bẹ̀rẹ̀ sí bọ́, ọ̀wààrà òjò bẹ̀rẹ̀ sí rọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA, nigbati iwọ jade kuro ni Seiri, nigbati iwọ nyan jade lati pápa Edomu wá, ilẹ mìtiti, awọn ọrun si kánsilẹ, ani awọsanma pẹlu kán omi silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“OLÚWA nígbà tí o jáde lọ láti Ṣéírì, nígbà tí o yan láti ilẹ̀ Édómù, ilẹ̀ mì tìtì, àwọn ọ̀run ya, ìkúùkù àwọ̀sámọ̀ da omi wọn sílẹ̀.