Judges 5:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ìgbà ayé Ṣamgari, ọmọ Anati, ati nígbà ayé Jaeli, ọ̀wọ́ èrò kò rin ilẹ̀ yìí mọ́, àwọn arìnrìnàjò sì ń gba ọ̀nà kọ̀rọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ́ Ṣamgari ọmọ Anati, li ọjọ́ Jaeli, awọn ọ̀na opópo da, awọn èro si nrìn li ọ̀na ìkọ̀kọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní àwọn ọjọ́ Ṣámgárì ọmọ Ánátì, Ní àwọn ọjọ́ Jáélì, a kọ àwọn ojú ọ̀nà sílẹ̀; àwọn arìnrìnàjò ń gba kọ̀rọ̀ kọ́rọ́.