Judges 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo ìlú dá wáí ní Israẹli, ó dá, gbogbo ìlú di àkọ̀tì, títí tí ìwọ Debora fi dìde, bí ìyá, ní Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn olori tán ni Israeli, nwọn tán, titi emi Debora fi dide, ti emi dide bi iya ni Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn akọni ìletò dínkù, wọ́n dínkù afi ìgbà tí Dèbórà dìde, ó dìde bí ìyá ní Ísírẹ́lì.