Judges 5:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní gbogbo ìgbà tí àwọn ọmọ Israẹli dá oriṣa titun, ogun bo gbogbo ẹnubodè. Ninu bí ọ̀kẹ́ meji (40,000) ọkunrin tí wọ́n wà ní Israẹli, ǹjẹ́ a rí ẹnikẹ́ni tí ó ní apata tabi ọ̀kọ̀?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti yàn ọlọrun titun; nigbana li ogun wà ni ibode: a ha ri asà tabi ọ̀kọ kan lãrin ẹgba ogún ni Israeli bi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Ísírẹ́lì bá yan Ọlọ́run àjèjì, ogun jíjà wọ ibodè ìlú a kò rí àpáta tàbí ọ̀kọ̀ láàárin àwọn ẹgbàá ní Ísírẹ́lì