Judges 5:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọkàn mi lọ sọ́dọ̀ àwọn balogun Israẹli, tí wọ́n fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀ láàrin àwọn eniyan. Ẹ fi ìyìn fún OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Àiya mi fà si awọn alaṣẹ Israeli, awọn ti nwọn fi tinutinu wá ninu awọn enia: ẹ fi ibukún fun OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Inú mi yọ̀ sí àwọn aláṣẹ Ísírẹ́lì àwọn tí ó fi tínu tínu fi ara wọn rúbọ Ẹ yín OLÚWA!