Judges 6:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fi wọ́n lé àwọn ará Midiani lọ́wọ́ fún ọdún meje.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
AWỌN ọmọ Israeli si ṣe buburu loju OLUWA: OLUWA si fi wọn lé Midiani lọwọ li ọdún meje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì tún ṣe ohun tí ó burú ní ojú OLÚWA, Ó sì fi wọ́n lé àwọn ará Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.