Judges 6:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ni angẹli OLUWA náà yọ sí i, ó sì wí fún un pé, “OLUWA wà pẹlu rẹ, ìwọ akikanju ati alágbára ọkunrin.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Angeli OLUWA na si farahàn a, o si wi fun u pe, OLUWA wà pẹlu rẹ, iwọ ọkunrin alagbara.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ańgẹ́lì OLÚWA fara han Gídíónì, ó wí fún un pé, “OLÚWA wà pẹ̀lú rẹ, akọni ológun.”