Judges 6:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni Gideoni tó mọ̀ pé angẹli OLUWA ni, ó bá dáhùn pé, “Yéè! OLUWA Ọlọrun, mo gbé! Nítorí pé mo ti rí angẹli OLUWA lojukooju.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gideoni si ri pe angeli OLUWA ni; Gideoni si wipe, Mo gbé, OLUWA Ọlọrun! nitoriti emi ri angeli OLUWA li ojukoju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí Gídíónì sì ti mọ̀ dájúdájú pé ańgẹ́lì OLÚWA ni, ó ké wí pé, “Háà! OLÚWA Ọlọ́run alágbára! Mo ti rí ańgẹ́lì OLÚWA ní ojú korojú!”