Judges 7:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ bomi, tí wọ́n sì fi ahọ́n lá a bí ajá jẹ́ ọọdunrun (300), gbogbo àwọn yòókù ni wọ́n kúnlẹ̀ kí wọ́n tó mu omi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iye awọn ẹniti o lá omi, ti nwọn fi ọwọ́ wọn si ẹnu wọn, jẹ́ ọdunrun ọkunrin: ṣugbọn gbogbo awọn enia iyokù kunlẹ li ẽkun wọn lati mu omi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin ni ó lá omi pẹ̀lú ahọn wọn. Gbogbo àwọn ìyókù ni ó kúnlẹ̀ láti mu mi.