Judges 8:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà ó lọ sí Penueli, ó wó ilé ìṣọ́ wọn, ó sì pa àwọn ọkunrin ìlú náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si wó ile-ẹṣọ́ Penueli, o si pa awọn ọkunrin ilu na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wọ ilé ìṣọ́ Péníélì, ó sì pa àwọn ọkùnrin ìlú náà.