Judges 8:30 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aadọrin ọmọ ni Gideoni bí, nítorí pé ó ní ọpọlọpọ aya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gideoni si ní ãdọrin ọmọkunrin ti o bi fun ara rẹ̀: nitoripe o lí obinrin pupọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àádọ́rin ọmọ ni ó bí, nítorí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìyàwó.