Judges 9:50 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Abimeleki tún lọ sí Tebesi, ó gbógun tì í, ó sì gbà á.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Abimeleki lọ si Tebesi, o si dótì Tebesi, o si kó o.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ábímélékì tún lọ sí Tébésì, ó yí ìlú náà ká pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun, ó sì ṣẹ́gun rẹ̀.