Lamentations 1:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ó rán iná láti òkè ọ̀run wá; ó dá a sí egungun mi; ó dẹ àwọ̀n sílẹ̀ fún mi; ó sì dá mi pada. Mo dàbí odi, mo sì fi ìgbà gbogbo dákú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati oke li a ti rán iná sinu egungun mi, o si ràn ninu rẹ̀: On ti nà àwọn fun ẹsẹ mi, o ti yi mi pada sẹhin; O ti mu mi dahoro, mo si rẹ̀wẹsi lojojumọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ó rán iná láti òkè sọ̀kalẹ̀ sínú egungun ara mi. Ó dẹ àwọ̀n fún ẹsẹ̀ mi, ó sì yí mi padà. Ó ti pa mí lára mó ń kú lọ ní gbogbo ọjọ́.