Lamentations 1:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ranti gbogbo ìwà ibi wọn, kí o sì jẹ wọ́n níyà; bí o ti jẹ mí níyà, nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi. Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì rẹ̀wẹ̀sì.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki gbogbo ìwa-buburu wọn wá si iwaju rẹ; si ṣe si wọn, gẹgẹ bi iwọ ti ṣe si mi nitori gbogbo irekọja mi: nitori ikẹdùn mi pọ̀, ọkàn mi si rẹ̀wẹsi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Jẹ́ kí ìwà ìkà wọn wá síwájú rẹ; jẹ wọ́n níyà bí o se jẹ mí níyà nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi. Ìrora mi pọ̀ ọkàn mi sì káàárẹ̀.”