Lamentations 2:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹkún sísun ti sọ ojú mi di bàìbàì, ìdààmú bá ọkàn mi; ìbànújẹ́ sì mú kí ó rẹ̀wẹ̀sì nítorí ìparun àwọn eniyan mi, nítorí pé àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ ati àwọn ọmọ ọwọ́ ń dákú lójú pópó láàrin ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi gbẹ tan fun omije, inu mi nho, a dà ẹ̀dọ mi sori ilẹ, nitori iparun ọmọbinrin awọn enia mi: nitoripe awọn ọmọ wẹ̃rẹ ati awọn ọmọ-ọmu nkulọ ni ita ilu na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú mi kọ̀ láti sunkún, mo ń jẹ ìrora nínú mi, mo tú ọkàn mi jáde sí ilẹ̀ nítorí a pa àwọn ènìyàn mí run, nítorí àwọn ọmọdé àti ọmọ ọwọ́ ń kú ní òpópó ìlú.