Lamentations 2:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ dìde, ẹ kígbe lálẹ́, ní àkókò tí àwọn aṣọ́de ń bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́! Ẹ tú ẹ̀dùn ọkàn yín jáde bí omi níwájú OLUWA! Ẹ gbé ọwọ́ ẹ̀bẹ̀ sókè sí i, nítorí ẹ̀mí àwọn ọmọ yín tí ebi ń pa kú lọ ní gbogbo ìkóríta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dide, kigbe soke li oru ni ibẹrẹ akoko iṣọ: tú ọkàn rẹ jade gẹgẹ bi omi niwaju Oluwa: gbe ọwọ rẹ soke si i fun ẹmi awọn ọmọ wẹwẹ rẹ, ti nkulọ fun ebi ni gbogbo ori-ita.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dìde, kígbe sókè ní àsálẹ́, bí ìṣọ́ òru ti bẹ̀rẹ̀ tú ọkàn rẹ̀ jáde bí omi níwájú OLÚWA. Gbé ọwọ́ yín sókè sí i nítorí ẹ̀mí àwọn èwe rẹ̀ tí ó ń kú lọ nítorí ebi ní gbogbo oríta òpópó.