Lamentations 3:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó mú gbogbo ọfà tí ó wà ninu apó rẹ̀ ó ta wọ́n mọ́ mi lọ́kàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O ti mu ki ọfà apó rẹ̀ wọ inu-ẹdọ mi lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó fa ọkàn mí ya pẹ̀lú ọfà nínú àkọ̀ rẹ̀.