Lamentations 3:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mò ń ranti nígbà gbogbo, ọkàn mi sì ń rẹ̀wẹ̀sì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lõtọ, nigbati ọkàn mi nṣe iranti wọn, o si tẹriba ninu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo ṣèrántí wọn, ọkàn mi sì gbọgbẹ́ nínú mi.