Lamentations 3:25 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA a máa ṣe oore fún àwọn tí wọn dúró dè é, tí wọn sì ń wá ojurere rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa ṣe rere fun gbogbo ẹniti o duro dè e, fun ọkàn ti o ṣafẹri rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dídára ni OLÚWA fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.