Lamentations 3:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ó tilẹ̀ mú kí ìbànújẹ́ dé bá wa, yóo ṣàánú wa, yóo tù wá ninu, gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o tilẹ mu ibanujẹ wá, sibẹ on o ni irọnu gẹgẹ bi ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lóòtọ́ ó mú ìbànújẹ́ wá, yóò fi àánú hàn, nítorí náà títóbi ni ìfẹ́ rẹ̀.