Lamentations 3:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé kì í kàn déédé ni eniyan lára tabi kí ó mú ìbànújẹ́ dé bá eniyan láìní ìdí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori on kì ifẹ ipọn-ni-loju lati ọkàn rẹ̀ wá, bẹ̃ni kì ibà ọmọ enia ninu jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí kò mọ̀ọ́mọ̀ mú ìpọ́njú wá tàbí ìrora wá fún ọmọ ènìyàn.