Lamentations 3:51 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìbànújẹ́ bá mi, nígbà tí mo rí ibi tí ó ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọmọbinrin ìlú mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi npọn ọkàn mi loju, nitori gbogbo awọn ọmọbinrin ilu mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohun tí mo rí mú ìbẹ̀rù wá ọkàn mi nítorí gbogbo àwọn obìnrin ìlú mi.