Lamentations 3:53 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n jù mí sinu ihò láàyè, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí sọ òkúta lù mí mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti ke ẹmi mi kuro ninu iho, nwọn si yi okuta sori mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gbìyànjú láti mú òpin dé bá ayé mi nínú ihò wọ́n sì ju òkúta lù mí.

Recommended Reading