Lamentations 4:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn obinrin tí wọn ní ojú àánú ti fi ọwọ́ ara wọn se ọmọ wọn jẹ, wọ́n fi ọmọ wọn ṣe oúnjẹ jẹ, nígbà tí ìparun dé bá àwọn eniyan mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọwọ awọn obinrin alãnu ti sè awọn ọmọ awọn tikarawọn: awọn wọnyi li ohun jijẹ fun wọn ni igba wahala ọmọbinrin awọn enia mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú ọwọ́ àwọn obìnrin aláàánú ni wọ́n ṣe ọmọ wọn tí ó di oúnjẹ fún wọn nígbà tí a pa àwọn ènìyàn mi run.