Lamentations 4:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wolii rẹ̀ ló fa èyí, ati àìdára àwọn alufaa rẹ̀, tí wọ́n pa olódodo láàrin ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ẹ̀ṣẹ awọn woli rẹ̀, ati aiṣedede awọn alufa rẹ̀, ti nwọn ti ta ẹ̀jẹ awọn olododo silẹ li ãrin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn wòlíì àti àìṣedédé àwọn olórí àlùfáà, tí ó ta ẹ̀jẹ̀ àwọn olódodo sílẹ̀ láàrin rẹ̀.