Lamentations 4:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ń káàkiri bí afọ́jú láàrin ìgboro, ẹ̀jẹ̀ àwọn tí wọ́n pa sọ wọ́n di aláìmọ́ tóbẹ́ẹ̀ tí ẹnikẹ́ni kò lè fọwọ́ kan aṣọ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn ti rin kiri bi afọju ni ita, nwọn di alaimọ́ fun ẹ̀jẹ tobẹ̃ ti enia kò le fi ọwọ kan aṣọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nísinsìnyí wọ́n ń rìn kiri ní òpópó bí ọkùnrin tí ó fọ́jú. Ẹ̀jẹ̀ ara wọn sọ wọ́n di àbàwọ́n tí kò sẹ́ni tó láyà láti fọwọ́ kan aṣọ wọn.