Lamentations 4:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan ń ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ wa, tóbẹ́ẹ̀ tí a kò lè rìn gaara ní ìgboro. Ìparun wa súnmọ́lé, ọjọ́ ayé wa ti níye, nítorí ìparun wa ti dé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn dẹkun si ipa ọ̀na wa, ti awa kò le rìn ita wa: opin wa sunmọ tosi, ọjọ wa pé; nitori opin wa de.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ń ṣọ́ wa kiri, àwa kò sì le rìn ní òpópó wa mọ́. Òpin wa ti súnmọ́, ọjọ́ wa sì níye nítorí òpin wa ti dé.