Lamentations 4:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọn ń lépa wa yára ju idì tí ń fò lójú ọ̀run lọ. Wọ́n ń lé wa lórí òkè, wọ́n sì ba dè wá ninu aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti nlepa wa yara jù idì ọrun lọ: nwọn nlepa wa lori oke wọnni, nwọn bà dè wa li aginju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ń lé wa yára ju idì ojú ọ̀run lọ; wọ́n lé wa ní gbogbo orí òkè wọ́n sì gẹ̀gùn dè wá ní ihà.