Lamentations 4:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ wo àwọn ọdọmọkunrin Sioni, àwọn ọmọ tí wọn níye lórí bí ojúlówó wúrà, tí a wá ń ṣe bí ìkòkò amọ̀; àní, bí ìkòkò amọ̀ lásánlàsàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ iyebiye Sioni, ti o niye lori bi wura didara, bawo li a ṣe kà wọn si bi ikoko amọ̀, iṣẹ ọwọ alamọ̀!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báwo ni àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Síónì tí ó ṣe iyebíye, tí wọ́n wọn iye wúrà ṣe wá dàbí ìkòkò amọ̀ lásán iṣẹ́ ọwọ́ amọ̀kòkò!