Lamentations 4:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀mí àwa ẹni àmì òróró OLUWA bọ́ sinu kòtò wọn, OLUWA tí à ń sọ nípa rẹ̀ pé, lábẹ́ òjìji rẹ̀ ni a óo máa gbé láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẽmi iho imu wa, ani ẹni-ororo Oluwa, ni a mu ninu ọ̀fin wọn, niti ẹniti awa wipe, labẹ ojiji rẹ̀ li awa o ma gbé lãrin awọn orilẹ-ède.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni àmì òróró OLÚWA, èémí ìyè wa, ni wọ́n fi tàkúté wọn mú. Àwa rò pé lábẹ́ òjìji rẹ̀ ni àwa yóò máa gbé láàrin orílẹ̀-èdè gbogbo.