Lamentations 4:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ajáko a máa fún àwọn ọmọ wọn lọ́mú. Ṣugbọn àwọn eniyan mi ti di ìkà, bí ògòǹgò inú aṣálẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ani ọ̀wawa nfà ọmu jade, nwọn nfi ọmu fun awọn ọmọ wọn: ṣugbọn ọmọbinrin awọn enia mi ti di ìka, gẹgẹ bi abo ògongo li aginju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀wàwà pèsè ọmú wọn fún ìtọ́jú àwọn ọmọ wọn, ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn mi wá láì lọ́kàn bí ògòǹgò ní aṣálẹ̀.