Lamentations 4:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn tí wọn tí ń jẹ oúnjẹ àdídùn di ẹni tí ń ṣa ilẹ̀ jẹ kiri ní ìgboro. Àwọn tí wọn tí ń fi aṣọ àlàárì bora di ẹni tí ń sùn lórí òkítì eérú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o ti njẹ ohun didùndidùn nkú lọ ni ita: awọn ti a ti tọ́ ninu aṣọ-òdodó, gbá ãtàn mọra.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó ń jẹ ohun dáradára di òtòsì ní òpópó. Àwọn tí a fi aṣọ dáradára wọ̀ ni wọ́n sùn ní orí òkítì eérú.