Lamentations 4:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìjìyà àwọn eniyan mi pọ̀ ju ti àwọn ará Sodomu lọ, Sodomu tí ó parun lójijì, láìjẹ́ pé eniyan fi ọwọ́ kàn án.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori aiṣedede ọmọbinrin awọn enia mi tobi jù ẹ̀ṣẹ Sodomu lọ, ti a bì ṣubu ni iṣẹju, laisi iṣiṣẹ ọwọ ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjìyà àwọn ènìyàn mi tóbi ju ti Sódómù lọ, tí a sí nípò ní òjijì láì sí ọwọ́ láti ràn án lọ́wọ́.