Lamentations 4:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn nisinsinyii, ojú wọn dúdú ju èédú lọ, kò sí ẹni tí ó dá wọn mọ̀ láàrin ìgboro, awọ ara wọn ti hunjọ lórí egungun wọn, wọ́n wá gbẹ bí igi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju wọn dudu jù ẽdu nisisiyi; a kò mọ̀ wọn ni ita: àwọ wọn lẹ mọ egungun wọn; o di gbigbẹ gẹgẹ bi igi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n nísinsìn yìí wọ́n dúdú ju èédú; wọn kò sì dá wọn mọ̀ ní òpópó. Ara wọn hun mọ́ egungun; ó sì gbẹ bí igi gbígbẹ.