Lamentations 4:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ti àwọn tí wọ́n kú ikú ogun sàn ju àwọn tí wọ́n kú ikú ebi lọ, àwọn tí ebi pa joró dójú ikú, nítorí àìsí oúnjẹ ninu oko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti a fi idà pa san jù awọn ti a fi ebi pa, ti ndaku, ti a gún wọn lara nitori aisi eso-oko.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí ó kù nípasẹ̀ idà sàn ju àwọn tí ìyàn pa; tí ó wọ àkísà ebi, tí ó ń ṣòfò fún àìní oúnjẹ láti inú pápá.

Recommended Reading