Lamentations 5:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn àgbààgbà ti sá kúrò ní ẹnubodè; àwọn ọdọmọkunrin sì ti dákẹ́ orin kíkọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn àgbagba dasẹ kuro li ẹnu-bode, awọn ọdọmọkunrin kuro ninu orin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àgbààgbà ti lọ kúrò ní ẹnu bodè ìlú; àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì dákẹ́ orin wọn