Lamentations 5:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A ti fa ara wa kalẹ̀ fún àwọn ará Ijipti ati àwọn ará Asiria nítorí oúnjẹ tí a óo jẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awa ti fi ọwọ wa fun awọn ara Egipti, ati fun ara Assiria, lati fi onjẹ tẹ́ wa lọrùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwa jọ̀wọ́ ara wa fún Éjíbítì àti Ásíríà láti rí oúnjẹ tótó jẹ.