Lamentations 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn baba wa ni wọ́n dẹ́ṣẹ̀, àwọn sì ti kú, ṣugbọn àwa ni à ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn baba wa ti ṣẹ̀, nwọn kò si sí; awa si nrù aiṣedede wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn baba wa ti ṣẹ̀, wọn kò sì sí mọ́, àwa sì ń ru ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.