Leviticus 12:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tí ó bá di ọjọ́ kẹjọ, wọn yóo kọ ilà abẹ́ fún ọmọ náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni ijọ́ kẹjọ ni ki a si kọ ọmọkunrin na nilà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ kẹjọ ni kí ẹ kọ ọmọ náà ní ilà.