Leviticus 16:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn tí meji ninu àwọn ọmọ Aaroni kú, nígbà tí wọ́n fi iná tí kò mọ́ rúbọ sí OLUWA, OLUWA bá sọ fún Mose pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si sọ fun Mose lẹhin ikú awọn ọmọ Aaroni meji, nigbati nwọn rubọ niwaju OLUWA, ti nwọn si kú;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sọ fún Mósè lẹ́yìn ikú àwọn ọmọ Árónì méjèèje tí wọ́n kú nígbà tí wọ́n súnmọ́ OLÚWA.