Leviticus 16:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà yóo mú àwọn ewúrẹ́ mejeeji, yóo fà wọ́n kalẹ̀ níwájú OLUWA, ní ẹnu ọ̀nà Àgọ́ Àjọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki o si mú ewurẹ meji nì, ki o si mú wọn wá siwaju OLUWA si ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà yóò sì mú ewúrẹ́ méjì náà wá sí iwájú OLÚWA ní ibi ilẹ̀kùn àgọ́ ìpàdé.