Leviticus 17:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn, tí kò bá fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ̀, yóo jìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bi kò ba fọ̀ wọn, tabi ti kò si wẹ̀ ara rẹ̀; njẹ on o rù ẹ̀ṣẹ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n bí ó bá kọ̀ láti wẹ ara rẹ̀ tí kò sì fọ aṣọ rẹ̀ náà: ẹ̀bi rẹ̀ yóò wà lórí ara rẹ̀.’ ”