Leviticus 24:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òfin kan náà tí ó de àlejò, ni ó gbọdọ̀ de onílé, nítorí pé èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Irú ofin kan li ẹnyin o ní, gẹgẹ bi fun alejò bẹ̃ni fun ibilẹ: nitoripe Emi li OLUWA Ọlọrun nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òfin kan náà ló wà fún àlejò àti fún ọmọ Ísírẹ́lì. Èmi ni OLÚWA Ọlọ́run yín.’ ”