Leviticus 25:52 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ọdún tí ó kù tí ọdún jubili yóo fi pé kò bá pọ̀ mọ́, wọn yóo jọ ṣírò iye ọdún tí ó kù fún un láti fi sìn ín, òun ni yóo sì fi ṣírò owó ìràpadà rẹ̀ tí ó kù tí yóo san.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ba si ṣepe kìki ọdún diẹ li o kù titi di ọdún jubeli, njẹ ki o ba a ṣìro, gẹgẹ bi iye ọdún rẹ̀ ni ki o san owo ìrasilẹ rẹ̀ pada.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ọdún rẹ̀ kò bá pọ̀ sí àkókò ìdásílẹ̀, kí ó ṣe ìṣírò rẹ̀, kí ó sì san owó náà bí iye ìṣírò rẹ̀.