Leviticus 26:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo fọ́n yín káàkiri ààrin àwọn orílẹ̀-èdè, idà ni wọn yóo máa fi pa yín ní ìpakúpa, ilẹ̀ yín ati àwọn ìlú yín yóo di ahoro.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o si tú nyin ká sinu awọn orilẹ-ède, emi o si yọ idà tì nyin lẹhin: ilẹ nyin yio si di ahoro, ati ilu nyin yio di ahoro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mú ogun dé bá yín: Èmi yóò sì fọ́n yín ká gbogbo àwọn ilẹ̀ àjèjì, ilẹ̀ yín yóò sì di ahoro: àwọn ìlú yín ni a ó sì parun.