Leviticus 26:38 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ óo parun láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ilẹ̀ àwọn ọ̀tá yín yóo sì gbé yín mì.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹnyin o si ṣegbé ninu awọn orilẹ-ède, ilẹ awọn ọtá nyin yio si mú nyin jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin yóò ṣègbé láàrin àwọn orílẹ̀ èdè abọ̀rìṣà. Ilẹ̀ ọ̀ta yín yóò sì jẹ yín run.