Leviticus 4:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn àgbààgbà ninu àwọn eniyan náà yóo gbé ọwọ́ wọn lé orí akọ mààlúù yìí níwájú OLUWA, wọn óo sì pa á níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki awọn àgbagba ijọ enia ki o fi ọwọ́ wọn lé ori akọmalu na niwaju OLUWA: ki a si pa akọmalu na niwaju OLUWA.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì gbé ọwọ́ lórí akọ ọmọ màlúù náà níwájú OLÚWA.